Ẹ́sítà 4:2 BMY

2 Ṣùgbọ́n ó lọ sí ẹnu ọ̀nà ọba nìkan, nítorí kò sí ẹnìkan tí ó wọ aṣọ ọ̀fọ̀ tì a gbà láàyè láti wọ ibẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 4

Wo Ẹ́sítà 4:2 ni o tọ