Ẹ́sítà 4:5 BMY

5 Nígbà náà ni Ẹ́sítà pe Hátakì, ọ̀kan nínú àwọn ìwẹ̀fà ọba tí a yàn láti máa jíṣẹ́ fún-un, ó pàṣẹ fún un pé kí ó béèrè ohun tí ó ń dààmú Módékáì àti ohun tí ó ṣe é.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 4

Wo Ẹ́sítà 4:5 ni o tọ