Ẹ́sítà 5:14 BMY

14 Ìyàwó rẹ̀ Ṣérésì àti àwọn ọ̀rẹ́ẹ rẹ̀ wí fún-un pé, “Ri igi kan, kí ó ga tó ìwọ̀n míta mẹ́ta-lélógún, kí o sì sọ fún ọba ní òwúrọ̀ ọ̀la kí ó gbé Módékáì rọ̀ sórí i rẹ̀. Nígbà náà ni ìwọ yóò bá ọba lọ sí ibi àṣè pẹ̀lú ayọ̀.” Èrò yí dùn mọ́ Hámánì nínú, ó sì ri igi náà.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 5

Wo Ẹ́sítà 5:14 ni o tọ