Ẹ́sítà 5:3 BMY

3 Nígbà náà ni ọba béèrè pé, “kí ni ó dé, ayaba Ẹ́sítà? Kí ni o fẹ́? Bí ó tilẹ̀ ṣe títí dé ìdajìn mi ìjọba àní, a ó fi fún ọ.”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 5

Wo Ẹ́sítà 5:3 ni o tọ