Ẹ́sítà 5:6 BMY

6 Bí wọ́n ṣe ń mu wáìnì, ọba tún béèrè lọ́wọ́ Ésítà, “Báyìí pẹ́: kí ni ẹ̀bẹ̀ rẹ? A ó sì fi fún ọ. Kí ni ìwọ ń béèrè fún? Àní bí ó tilẹ̀ jẹ́ ìdajì ìjọbaa mi, a ó fi fún ọ.”

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 5

Wo Ẹ́sítà 5:6 ni o tọ