Ẹ́sítà 8:10 BMY

10 Modékáì sì fi àṣẹ ọba Ṣéríṣésì kọ̀wé, ó sì fi òrùka ọba ṣe èdìdì i rẹ̀, ó rán-an lọ ní kíákíá, ó sì rán àwọn ìránṣẹ́ ayaba, bí àṣà àwọn tí wọ́n ń gun ẹṣin tí ó yára, ní pàtàkì èyí tí a ń bọ́ fún ọba.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:10 ni o tọ