Ẹ́sítà 8:15 BMY

15 Módékáì sì kúrò níwájú ọba, ó wọ aṣọ aláró àti funfun, ó dé adé e wúrà ńlá pẹ̀lú ìgbànú eléṣèé àlùkò dáradára, ìlú Ṣúṣà sì ṣe àjọyọ̀ ńlá.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:15 ni o tọ