Ẹ́sítà 8:7 BMY

7 Ọba Ṣéríṣésì dá Ẹ́sítà ayaba àti Módékáì aráa Júù náà lóhùn pé, “Nítorí Hámánì kọ lu àwọn aráa Júù, èmi ti fi ilée rẹ̀ fún Ẹ́sítà, wọ́n sì ti ṣo ó kọ́ sórí igi.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 8

Wo Ẹ́sítà 8:7 ni o tọ