Ẹ́sítà 9:11 BMY

11 Ní ọjọ́ náà gan-an ni a mú iye àwọn tí a pa ní ilé ìṣọ́ ti Ṣúṣà wá fún ọba.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:11 ni o tọ