Ẹ́sítà 9:14 BMY

14 Nítorí náà ọba pàṣẹ pé kí a ṣe bẹ́ẹ̀. A sì gbé àṣẹ kan jáde ní Ṣúṣà, wọ́n sì so àwọn ọmọkùnrin mẹ́wẹ̀ẹ̀wá Hámánì kọ́.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:14 ni o tọ