Ẹ́sítà 9:17 BMY

17 Èyí ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù Ádárì, wọ́n sì sinmi ní ọjọ́ kẹrìnlá, wọ́n sì ṣe ọjọ́ náà ní ọjọ́ àṣè àti ayọ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:17 ni o tọ