Ẹ́sítà 9:2 BMY

2 Àwọn Júù pé jọ ní àwọn ìlú u wọn ní gbogbo agbégbé ọba Ṣéríṣésì láti kọlu àwọn tó ń wá ìparun wọn. Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè dojú kọ wọ́n, nítorí gbogbo àwọn ènìyàn ìlú tó kù ń bẹ̀rù u wọn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:2 ni o tọ