Ẹ́sítà 9:27 BMY

27 Àwọn Júù fi lélẹ̀, wọ́n sì gbàá gẹ́gẹ́ bí ìlànà fún ara wọn àti fún irú àwọn ọmọ wọn àti gbogbo àwọn tí ó dara pọ̀ mọ́ wọn, kò sì ní kúrò, wọn yóò sì máa pa àwọn ọjọ́ méjèèjì yìí mọ́ ní gbogbo ọdún, gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ àti àkókò tí a yàn.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 9

Wo Ẹ́sítà 9:27 ni o tọ