Hósíà 1:9 BMY

9 Olúwa sì sọ fún un pé, “Pe orúkọ rẹ̀ ní Lo-ámì, (kì í ṣe ènìyàn mi) nítorí pé ẹ kì í ṣe ènìyàn mi, èmi náà kì í sì í ṣe Ọlọ́run yín.

Ka pipe ipin Hósíà 1

Wo Hósíà 1:9 ni o tọ