Hósíà 10:15 BMY

15 Báyìí ni a o sì ṣe sí ọ, ìwọ Bétélì,nítorí pé ìwà buburú yín ti pọ̀jù.Ní àfẹ̀mọ́júmọ́ ọjọ́ náà,a o pa ọba Ísírẹ́lì run pátapáta.

Ka pipe ipin Hósíà 10

Wo Hósíà 10:15 ni o tọ