Hósíà 10:2 BMY

2 Ọkàn wọn kún fún ìtànjẹbáyìí wọ́n gbọdọ̀ ru ẹ̀bi wọn. Olúwa yóò wó pẹpẹ wọn palẹ̀yóò sì pa gbogbo òkúta ìyàsọ́tọ̀ wọn run.

Ka pipe ipin Hósíà 10

Wo Hósíà 10:2 ni o tọ