Hósíà 10:8 BMY

8 Àwọn ibi gíga tí ẹ tí ń hùwà buburú ni a o parun—Ẹ̀sẹ̀ Ísírẹ́lì ni.Ẹ̀gún ọ̀gàn àti ẹ̀gún òṣùṣú yóò hù jáde,yóò sì bo àwọn pẹpẹ wọn.Wọn yóò sọ fún àwọn òkè gíga pé, “Bò wá mọ́lẹ̀!”àti fún àwọn òkè kéékèèké pé, “Ṣubú lù wá!”

Ka pipe ipin Hósíà 10

Wo Hósíà 10:8 ni o tọ