Hósíà 12:1 BMY

1 Éfúráímù ń jẹ afẹ́fẹ́;Ó n lépa afẹ́fẹ́ ìwọ̀ oòrùn ní gbogbo ọjọ́.Ó sì ń gbèrú nínú irọ́Ó dá májẹ̀mú pẹ̀lú ÁsíríàÓ si fi òróró ólífì ránsẹ́ sí Éjíbítì.

Ka pipe ipin Hósíà 12

Wo Hósíà 12:1 ni o tọ