Hósíà 13:10 BMY

10 Níbo ni ọba rẹ gbé wà nìsisin yìí kí ó bá à le gbà ọ là?Níbo ni àwọn olórí ìlú yín wà,àwọn tí ẹ sọ pé,‘Fún wa ní ọba àti ọmọ aládé’?

Ka pipe ipin Hósíà 13

Wo Hósíà 13:10 ni o tọ