Hósíà 13:15 BMY

15 Bí ó tilẹ̀ gbilẹ̀ láàrin àwọn arákùnrin rẹ̀afẹ́fẹ́ ìlà oòrùn láti ọ̀dọ̀ Olúwa yóò wá,Yóò fẹ́ wá láti inú asálẹ̀orísun omi rẹ̀ yóò gbẹkànga rẹ̀ yóò gbẹpẹ̀lú olè yóò fọ́ ilé ẹrùàti gbogbo ilé ìṣúra rẹ̀

Ka pipe ipin Hósíà 13

Wo Hósíà 13:15 ni o tọ