13 Èmi yóò jẹ́ ẹ́ níyà fún gbogbo ọjọ́tó fi jo tùràrí sí Báálìtí ó fi òrùka àti ohun ọ̀ṣọ́ wọ ara rẹ̀ tán,tó sì tẹ̀lé àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ lọ.Ṣùgbọ́n ó gbàgbé èmi,”ni Olúwa wí.
Ka pipe ipin Hósíà 2
Wo Hósíà 2:13 ni o tọ