Hósíà 4:1 BMY

1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì,nítorí pé Olúwa fi ẹ̀sùnkan ẹ̀yin tí ń gbé ní ilẹ̀ náà.“Kò sí ìwà òtítọ́, kò sí ìfẹ́Kò sí ìmọ̀ Ọlọ́run ní ilẹ̀ náà

Ka pipe ipin Hósíà 4

Wo Hósíà 4:1 ni o tọ