Hósíà 6:9 BMY

9 Bí adigunjalè ṣe ń ba ní bùbá de àwọn ènìyànbẹ́ẹ̀ ni àwọn àlùfáà, ń parapọ̀;tí wọ́n sì ń pànìyàn lójú ọ̀nà tó lọ sí Ṣékémù,tí wọ́n sì ń dá ẹ̀ṣẹ̀ tí ó ti ni lójú.

Ka pipe ipin Hósíà 6

Wo Hósíà 6:9 ni o tọ