Hósíà 9:6 BMY

6 Bí wọ́n tilẹ̀ yọ́ kúrò lọ́wọ́ ìparunÉjíbítì yóò kó wọn jọ,Mémúfísì yóò sì sin wọ́n.Ibi ìsọjọ̀ sílífa wọn ni yèrèpè yóò jogún,Ẹ̀gún yóò bo àpótí ìṣúra fàdákà wọn.Ẹ̀gún yóò sì bogbogbo àgọ́ wọn.

Ka pipe ipin Hósíà 9

Wo Hósíà 9:6 ni o tọ