Léfítíkù 14:11 BMY

11 Àlùfáà tí ó pè é ní mímọ́: yóò mú ẹni náà tí a ó sọ di mímọ́ àti ọrẹ rẹ̀ wá ṣíwájú Olúwa ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:11 ni o tọ