Léfítíkù 14:12 BMY

12 “Kí àlùfáà mú ọ̀kan nínú àwọn àgbò àti òróró kí ó sì fi rú ẹbọ ẹbí. Kí ó sì fí wọn níwájú Olúwa gẹ́gẹ́ bí ẹbọ fífí.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:12 ni o tọ