Léfítíkù 14:34 BMY

34 “Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ Kénánì tí mo fi fún yín ni ìní, tí mo sì fí àrùn ẹ̀tẹ̀ sínú ile kan ní ilẹ̀ ìní yín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:34 ni o tọ