Léfítíkù 14:35 BMY

35 Kí ẹni tí ó ní ilọ̀ náà lọ sọ fún àlùfáà pé, ‘Èmi tí rí ohun tí ó jọ àrùn ẹ̀tẹ̀ ní ilé mi.’

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:35 ni o tọ