Léfítíkù 14:40 BMY

40 Àlùfáà yóò pàṣẹ kí a yọ àwọn òkúta tí àrùn náà ti bàjẹ́ kúrò kí a sì kó wọn dànù sí ibi tí a kà sí àìmọ́ lẹ́yìn ìlú.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:40 ni o tọ