Léfítíkù 14:41 BMY

41 Yóò sì mú kí wọ́n ha ògiri inú ilé náà yíká. Gbogbo ohun tí wọ́n fi rẹ́ ilé náà tí ó ti ha ni kí wọ́n kó dànù sí ibi tí a kà sí àìmọ́ lẹ́yìn ìlú náà.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:41 ni o tọ