Léfítíkù 14:42 BMY

42 Òkúta mìíràn ni kí wọ́n fi dípò àwọn tí a ti yọ dànù kí wọ́n sì rẹ́ ilé náà pẹ̀lú àwọn ohun ìrẹ́lé tuntun.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:42 ni o tọ