Léfítíkù 15:14 BMY

14 Ní ọjọ́ kẹjọ kí ó mú àdàbà méjì tàbí ọmọ ẹyẹlé méjì, kí ó sì wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé níwájú Olúwa, kí ó sì kó wọn fún àlùfáà.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:14 ni o tọ