Léfítíkù 15:15 BMY

15 Kí àlùfáà fi wọ́n rúbọ: ọ̀kan fún ọrẹ ẹ̀ṣẹ̀ àti èkejì fún ọrẹ ẹbọ sísun níwájú Olúwa ní ipò ọkùnrin náà nítorí ìṣunjáde rẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:15 ni o tọ