Léfítíkù 15:21 BMY

21 Ẹnikẹ́ni tí ó bá fọwọ́ kan ibùsùn rẹ̀ gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀ kí ó sì wẹ̀, yóò sì wà ní ipò àìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:21 ni o tọ