Léfítíkù 15:22 BMY

22 Ẹnikẹ́ni tí ó bá fọwọ́ kan ohunkóhun tí ó bá jókòó lé gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì wẹ̀, yóò sì wà ní ipò àìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:22 ni o tọ