Léfítíkù 15:23 BMY

23 Ìbáà se ibùsùn tàbí ohunkóhun tí ó jókòó lé. Ẹnikẹ́ni tí ó bá fọwọ́ kàn án yóò jẹ̀ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:23 ni o tọ