Léfítíkù 15:24 BMY

24 “ ‘Bí ọkùnrin kan bá bá a lòpọ̀ tí nǹkan osù rẹ̀ sì kàn án lára, yóò jẹ́ aláìmọ́ fún ọjọ́ méje, gbogbo ibùsùn tí ọkùnrin náà bá sùn yóò jẹ́ aláìmọ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:24 ni o tọ