Léfítíkù 15:26 BMY

26 Ibùsùn tí ó wù kí ó sùn sí ní gbogbo ìgbà tí ẹ̀jẹ̀ náà ń wá yóò jẹ́ àìmọ́ bí ibùsùn rẹ̀ ṣe jẹ́ lákókò nǹkan oṣù rẹ̀. Gbogbo ohun tí ó bá jokòó lé yóò wà ní àìmọ́, gẹ́gẹ́ bí àkókò nǹkan oṣù rẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:26 ni o tọ