Léfítíkù 15:27 BMY

27 Ẹnikẹ́ni tí ó bá fọwọ́ kàn wọ́n yóò wà ní àìmọ́. Ó gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì wẹ̀ kí ó sì wà ní àìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:27 ni o tọ