Léfítíkù 2:15 BMY

15 Kí ẹ da òróró lé e lórí, kí ẹ sì fi tùràrí sí i, ó jẹ́ ọrẹ ohun jíjẹ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 2

Wo Léfítíkù 2:15 ni o tọ