Léfítíkù 2:16 BMY

16 Àlùfáà yóò sun ẹbọ ìrántí lára ọkà àti òróró náà, pẹ̀lú gbogbo tùràrí gẹ́gẹ́ bí ọrẹ tí a fi iná sun sí Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 2

Wo Léfítíkù 2:16 ni o tọ