Léfítíkù 22:3 BMY

3 “Sọ fún wọn pé: ‘Fún àwọn ìran tí ń bọ̀. Bí ẹnikẹ́ni nínú àwọn ọmọ yín tí kò mọ́ bá wá síbi ọrẹ mímọ́ tí àwọn ara Ísírẹ́lì ti yà sọ́tọ̀ fún Olúwa, kí ẹ yọ ẹni náà kúrò nínú iṣẹ́ àlùfáà ní iwájú mi. Èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 22

Wo Léfítíkù 22:3 ni o tọ