Léfítíkù 22:4 BMY

4 “ ‘Bí ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Árónì bá ní àrùn ara tí ń ran ni, tàbí ìtújáde nínú ara. Ó lè má jẹ ọrẹ mímọ́ náà títí di ìgbà tí a ó fi wẹ̀ ẹ́ mọ́. Òun tún lè di aláìmọ́ bí ó bá fọwọ́ kan ohunkóhun tí òkú nǹkan bá sọ di àìmọ́ tàbí bí ó bá farakan ẹnikẹ́ni tí ó ní ìtújáde.

Ka pipe ipin Léfítíkù 22

Wo Léfítíkù 22:4 ni o tọ