Léfítíkù 27:5 BMY

5 Bí ẹni náà bá jẹ́ ọmọ ọdún márùn-ún sí ogún ọdún, kí iye owó rẹ̀ jẹ́ ogún ṣékélì fún ọkùnrin àti òṣùwọ̀n ṣékélì mẹ́wàá fún obìnrin.

Ka pipe ipin Léfítíkù 27

Wo Léfítíkù 27:5 ni o tọ