Léfítíkù 27:6 BMY

6 Bí ẹni náà bá jẹ́ ọmọ oṣù kan sí ọdún márùn-ún, kí iye owó rẹ̀ jẹ́ òṣùwọ̀n ṣékélì fàdákà márùn-ún fún ọkùnrin àti òṣùwọ̀n ṣékélì fàdákà mẹ́ta fún obìnrin.

Ka pipe ipin Léfítíkù 27

Wo Léfítíkù 27:6 ni o tọ