Léfítíkù 4:21 BMY

21 Lẹ́yìn náà ni yóò sun màlúù yìí lẹ́yìn ibùdó, yóò sì sun ún gẹ́gẹ́ bó se sun màlúù àkọ́kọ́. Èyí ni ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ fún gbogbo ijọ ènìyàn Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:21 ni o tọ