Léfítíkù 4:22 BMY

22 “ ‘Bí olórí kan bá ṣèèṣì ṣẹ̀ láìmọ̀ tí ó sì ṣe ohun tí kò yẹ kí ó ṣe sí ọ̀kan nínú àwọn òfin Olúwa Ọlọ́run rẹ̀, ó jẹ̀bi.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:22 ni o tọ