Léfítíkù 4:26 BMY

26 Kí ó sun gbogbo ọ̀rá rẹ̀ lórí pẹpẹ bí ó se sun ọ̀rá ọrẹ àlàáfíà. Báyìí ní àlùfáà yóò ṣe ètùtù fún ẹsẹ ọkùnrin náà, a ó sì dárí jìn-ín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:26 ni o tọ