Léfítíkù 4:27 BMY

27 “ ‘Bí ènìyàn nínú àwọn ará ìlú bá ṣèèṣì ṣẹ̀ láìmọ̀ tí ó sì se ohun tí kò yẹ sí ọkan nínú àwọn òfin Olúwa, ó jẹ̀bi.

Ka pipe ipin Léfítíkù 4

Wo Léfítíkù 4:27 ni o tọ