Léfítíkù 9:10 BMY

10 Ó sun ọ̀rá, kíndìnrín àti ọ̀rá tó bo ẹ̀dọ̀, èyí tó mú láti inú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, lórí pẹpẹ bí Olúwa ti pá láṣẹ fún Mósè.

Ka pipe ipin Léfítíkù 9

Wo Léfítíkù 9:10 ni o tọ